Title: TALO LO KU RE?
SCENE ONE
(Light
reveals to empty stage, we hard Rotimi voice from the back stage).
Rotimi: I said
leave my house (shouting and pushing him out).
Bro. Tola:
But Sir, Jesu feran yin ……. Cut in
Rotimi: Listen
carefully, any day tim ba tu ri o nibi, I will get you down.
Dele: But bro
da mi, ete gbo nan.
Rotimi: Excuse
me! (he left the stage)
Dele: Bro.
Tola, ejo ewa malo, tori aafe lu mu mi pa loni
(she walk in
with fear).
SCENE TWO
(Light
reveals to Betty and Caro discussing about Rotim)
Betty: Wo mo
tin date bobo kan unsin, in fact omo ni.
Caro: Yes,
mafipamon funmi lohun, gbe sim leti gbo.
Betty: Common
Caro, farare bale ma gist e (she stood up) To ba r bobo yi, ah! Wagba pe omo tan sibe. Se ti iduro e lasan ni, abi ta won
authentic to manju wo. Cacro maje hun soro ju, o bo wa pick me any time from now. Wari.
Caro: Hun hun,
okay o (dusting powder) A knock from the door.
Betty: Yes,
come in.
Rotimi: Hello
Baba.
Betty: Ah Roti
welcome (she huge him)
Rotimi: Omo
sowa pa
Betty: Mo wa
okay, meet my friend Caro.
Rotimi: Hello
Caro, is my pleasure (shaking her)
Caro: Hi!
Rotimi: Shall
we leave, Betty?
Rotimi: Caro
so take care of yourself.
Caro: Okay
bye. Hun God make I too get my oooo
SCENE THREE
(Light
reveals to Dele, Bimpe and Tola prayng for Rotimi).
Bimpe: Ah!
A o tun gbadura pe ki Oluwa fi okan awon unbeliever lewa lowo. Adura (they pick it up).
Dele: In Jesus
name we have prayed. (He raise a song). Ologun loluwa!! Jehovah nissa ……. Amen. A o tun lo gba adura pe ki Oluwa
ki o gba okan arakunrin Rotimi la lowo ewu ese. Adura.
Tola: In Jesus
name we have prayed. Baba ni oruko Jesu, ni oruko nla ti Jesu, Oluwa adupe fun anfani miran bi eyi, Baba e gba ope wa. Oluwa
e gba iyin wa. Oluwa awa gbadura wipe ki e tu broad Rotimi sile lowo ese, Oluwa esi won loju emi. Adupe nitori wipe adura
wa ti ditewo gba …… cut out.
SCENE FOUR
(Light
reveals to the gate of Hell. We see an angel standing
opposite
the devil before the gate)
Angle: Kuro
lodo mi, toripe o ye fun ile ologo.
Bakunle: Ah,
ah, kilode, mo se ohun toto nile aiye, mofi owo ati oro mi mon talaka niti anu sise koda mo fi owo mi ko le Oluwa, ati pe
idamewa mi n lo dede, m kosi salai ma bawon da owo ore abe iwasu. Mi ki pa ilejosin je, kilo tunwa ku mi ku.
Angel: Pelu
gbogbo awon awijare wony, o ye fun ile ologo o o.
Rotimi: (He
appear with surprise) ah, ah, iranse Olorun, ika moni o, laduru gbogbo iserere ti arakunrin yi kakale, otun wa ni ko ye fun
ile ologo. Owu, Olorun gan ko roro tobyun abi! Baba esi dasi.
Baba: Beni,
otito lokuru so. Sugbon, gbogbo ise ribiribi tokakale yi asan lonje, bohun gan tikalare o ba ti deni igbala kuro ninu ese.
Lotito mofi
isere mon Oluwa, sugbon ko fi okan re mon. Fun idi eyi, kolipin ninu ile ologo to fe wo yi. (pointing to the devil) orun apadi
ni ipin re.
Rotimi: Ah!
Baba, tawa loni okure ba yi.
Baba: Hun (shaking
his head) wo eleru ti setan ati gberu re.
Rotimi: Ah!
Baba, won o si salu fun mi.
Baba: Anu abi
kilo pe, ko sanu nikorita ti awa yi mon, toripe otiku. Be sini ati filele ninu iwe mimo pe leyin iku idajo lokan.
Rotimi: Ah!
Idajo.
Baba: Tawa
gan loni oku tire gan bayi?
Rotimi: (Looking
with surprise) . . . . cut out. Light fade.
SCENE FIVE
(Light
reveals to Rotimi coming out to the stage and thinking about the dream)
Rotimi: Ah
iru awon ala buruku wo n mo wan la lelu jometa yi nan? Talo noku mi, this is terrible, abi, I don’t understand (he move
towards the curtain).
Dele: Broda
mi, oto ni, talo ni oku yin pelu gbo awon iwa ti en wu won yi. (se move closer to him) broad mi sebi lati gba ti mon mi ti
salaisi, ni iwa yin ti yato. Broad mi adara beba le jawo kuro ninu awon iwa wonyi tesi fayeyin fun Jesu …. Cut in.
Rotimi: (he
slap her) keep short, (he goes in)
Dele: (crying)
Oluwa, Oluwa gba broda mi la kuro ninu ese.
SCENE SIX
(Light
reveals to Dele and Tola in Tola’s house).
Tola: Ah, Oga
o.
Dele: Bo ti
ri ni ye o bro Tola (she started crying)
Tola: Sis.
Dele, otito, e ma sukun mon, adura loro won nilo bay. Olorun tofi revelation ye han won, atun fi omiran tolagbara han won
leyi ti o bawon leru to be gee, tanfi jowo aiye won fun Kristi. Dandan n k’Olorun yi aiye won pada tori Olorun wa o
fe ku elese, af koronu piwada. Oluwa a se mo mon.
Dele: Amen.
Tola: Kristi
ma gba gbogbo ogo lori aiye won. Eje ka gbadura … cut out.
Light fade.
SCENE SEVEN
(Light
reveals to Rotimi and Caro coming from back stage, then Betty came in).
Betty: What
Caro? Rotimi ki … ki …… so Rotimi ah!
Rotimi: You
see …… Betty …. Let me …….. let (cut in).
Betty: Keep
short, you think you can use me and dump me abi ah Rotimi mayo eleyi. Ma foju re ri (light fade).
SCENE EIGHT
(Light
reveals to Hell fire where we see a lot of people crying
and
telling other what brought them to hell).
Shola: Seb
emi ati boy friend mi lalo si party amu oniruru oti be lasi jo si oniruru orin, ibe ni iya nla kan ti be sile nitori mi, kato
wi katofo iku t wole oti mu mi lo … ni …. Ni moba bara mi ni bi (crying). They all cry again.
Wale: Nigba
ti abere ipejo po awon omo Olorun ni secondary school ni won ba yan mi ni Treasurer. Iya mi o lowo be ni baba mi o ni lati
fi sawon idanwo third term mi, se ni mo ya lara owo ti won ko si mi lowo bi Treasurer lati fi san owo ile iwe mi laiso fun
eni kankan tori itiju. Lotito ni mo pinu ati da pada ni kete ti moba ri. Sa dede ni aisan nla kan dami dubule ti mi o si ni
ore ofe ati san owo nan tabi so fun enikeni titi olojo fide. Afi ti mo ba ra mi ni bi (crying).
Tayo: Ah! Egba
mi, mi o mon o, nba ti ba ore mi yan odi lati igba ti moti wani JSS 1 ni moti fi aye mi fun Jesu ti mo si ti datunbi, sugbon
sa ti mo de SS3 ni ore mi kan fesun ohun ti mi o se kan mi, oni pe ohun rimi ti moun gbe expo ninu idanwo SSCE ti a se tan,
ey lomulu be m nitori pe idoju ti loje fun mi ti mo si pinu pe hun oni dasi mon, ah! Ose keji re ni ku wole de, afi ti mo
ba ra mi nibi ah, mogbe egba m mo daran.
Gbenga: Ye,
moti gbe egba mi o! un oro pastor sosi wa ni emi ati awon ore mi pejo po ta n so, ati awon ti mo mon ri towase ati awon ohun
ti mi ki ri li mon so jade latari ati so asodun, ah sadede ni waya ilan ori ope ta duro si ja tosi bole minori, bi mo se barami
nibi nun o. (cryng) they all pick it all).
Mama: Mi o
mon, mi o mon o (crying) pe bi yio seri ni o mi ba ti atun se. Mo yan ale, mo jo run nina, koda oniruru ose ati perfumu aboni
lawo nimo man lo. Ni owuro odun ku ola ni mo ba iya egbe ile mi ja ti mo si se oniruru epe fun nitori omipipon lay mon pe
ori mi ni yio ti pada walo ja bi ase ko rawa sinu oko emi ati omo mi ta unlo sile odun, arin aginju ni oko wa ti gbana je,
ti emi ati omo mi kansoso si ba rawa nibi (pointing to the son) crying.
Son: Crying
….. ah, se bi iya mi logbe mi de bi, gbogbo igba to ba ba awon ara adugbo ja, ni yio timi pe kilo mon sepe fun won kn
si mon yan won lodi. Opo igba nan ni kin wa ma sofo fo baba mi fun awon. Atin ton se atin tan se ni hun mon wifun won torin
kan mon ba lanmi ah (crying). Light fade.
SCENE NINE
(Light
reveals to Rotimi confuse because of the dream).
Rotimi: Ah!
Oluwa mi o fe pari aiye mi sibi ekun ati ipayin keke yi …. Ah tani yio gba mi bayi? Dele, Dele (raise up to check her
in but could not find him) ah Oluwa gba mi abi (he hard a knock and Betty with two boys came in).
Betty: Rotimi,
Rotimi, ki lode ton sunkun? (she move closer as if she want to comfort her).
Rotimi: Ah
Betty mi ofe pari aiye mi sib iparun.
Betty: (she
laugh) Rotimi, o lo option, wo awon ore re (pointing at the two boys holding guns).
Rotimi: Ah
Betty (he was frightened) jo maje kin pari aiye mi bayi. Wo gbogbo to ba ni kin se ma se, I will do everything for you sake.
Betty: O mean
e! okay! Oka!! Ki ni opa iwo ati Caro po?
Rotimi: Ah!
Before man and God kosi ohun kankan larin wa. So ri ija temi ati e ja ni the other time yen, ohun lo wa bami fun pe kemi ati
e ka pari e.
Betty: Okay!
Did you still love me? Abi ofe mi mon?
Rotimi: Betty,
with all my heart, mo fe o (he move closer to her).
Betty: (she
pause) okay (laying hand on his shoulder) we shall see tomorrow. (she take some steps and look back to shoot him down).
Light fade.
LIGHT FADE
(Light
reveals to Rotimi at the gate)
Rotimi: Ah,
nibo ni mo wa yi?
Angel: Kabo,
ku irin osu ku ise ninu aiye. Ati fun o ni opolopo anfani lati fifun o, aimonye iran igba ikeyin lati fi han o, sugbon oseni
lanupe, leke gbogbo re o ko lati jewo Jesu ni Oluwa re.
Rotimi: Sugbon
mo je wo, mo je wo niwon ba eyi ti mo mon. mi ori eni tomi sona ni unba ku se ju bi moti se lo.
Angel: Awawi
o si niwaju ite idajo, toripe ojo tipe tan tin so fun o ni bayi, Olorun oga ogo ko loni oku re o o.
Voice: Kuro
lo do mi …. Iwo oni se ese, emi o moo riiiiiiiiiiii.
(The devil
came and take him away).
THE END